Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
1. ASEJE ATUDE
Ewe tude oojo, egbo tude oojo, ata ijosi ao lo
poao wa fi se ara eran maluekiri kan,fuku kiri
kan, edu kiri kan pelu isanu ti ao ti yio owo oja
kuro lara ni lepo niyo ao so kale si ori osukaa
o je pelu adura.
2. OSE ATUDE ASIONA
ao wa ewe akoko, epo igi akoko ati gbongbo i
di igiakoko ao gun po mose ao fi epo-pupa ra
ara ti ao to we odaju
3. ATUDE TIONA BADI
Ewe ajekobale die, ewe tude die,ewe mafiow
okanomomidie, ao lo po mo iyere ao fi se era
n basi kan je ni lepo ni yo. enikan ko gbodo fi
oju kan ise yiti ao ba fe je ale ni ao je ise yi ni i
hoho. ao da obe re si ilele ninu iyara wa ao ma
pe ogbolohun re si.
ofore:- yeye omo ni gba omo irukere nigba o
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
mo orunmila gbogbo ese ti alamu base idobal
e nifi tan idobale emi [L onmo L] ni o ki tude tu
gbogbo aburu ara mikuro, kin rije kin ri mu ki
nrina kin rilo gbogbo ide tin banbe lara mi ni k
iotu kuro nikiakia bayiao wa se adura si ao f
iidobale fie nu gbe basi eran na je ao la obe n
a bakana.
4. ATUDE ASIONA OLOJO KAN
Ori ako alangba tio ti gbo dada kan ao gun pe
luepo-obo ao fiose iwe ekan ko lojuolo ao fi
epo-pupa ra ara kiao to we. ose yi kin di ojo k
eji.
5. IWE TUDE ASIONA
Ewe taba oojo ewe ogbo oojo ao gbo ewe me
jjiyipapo dada ao gbe pamo diaro ojo keji ti
o badi aro ojo keji ki ao to ba nikeni soro ao lo
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
to siomi iwe yiao wa fi we pelu ose ituwo tab
itude ti ao ba ni ile.
6. IWE ATUDE NLA
Ewe efinrin tiko bal uoojo ao mu wole lo ao I
oao giose iwe ekan ko loju olo, sugbon laro k
utukutu ti aba tin ji laiti soro si enikeni ao to it
o idajiwa sibi kan di igba tiao lo we ose yi a
O wa muose yi losiodo pelu itO yen ao wa tui
to yi si oriwa dele ti a fi pa gbogbo ara wa a o
wa we ose yin ninu odo ti we tan ao ma lo si il
e sungbo ao gbudo we yin tiao fidele o-- by
alfa arindunnu
7. ETUTUASINA
ao lo ra akara elepo meta ao to sinu awo ipes
e ao da oyin gidi le loriao wa se adua si ao lo
gbesi ita ni ago mokanla ale.
Tby alfa -mons
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
uru
8. EYONUITUWO AROBI
Eye adan nla kan tope dada ti oni ifun ninu, egbo
tude oojo, odidi atare nla kan ao jo papo ao ro pa
mo, ao mafi epo pupa ogere la ninu awo sobi to
ti lo ti won tifi gbe ebo dada ti abati bu ebu yi si a
wO sobi yi ao teniodu oba ifa ao wa yasi lemata
pe ha,ha,ha opa karo eye ifa 3x opa ohun laja eye
onile 3X opa ota ta niewe olofin 3x awon meteta
niwon kenieyin kule orunmila orunmila ni ki ma
kenie o gbodo ha nitori iku tin be nile yi ko kan m
inieye adan nke arun tin be nile yi ko kan mi ni e
iye adan ke oriburuku, airina,arilo, ainilosiwaju ti
n be nile yi o kan mi nieiye adan nke gbogbo wa
hala, idamu tin be nile yio kan mi nieiye adan nk
e ao wa se adura si biao se fe ao wa fiika arin ro
ao wa la. (by Woli Irawo.
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
9. ATUDE AWON ELEYE TON SI ONA
ao wa obiabata alawe meta ao la iko kan nibe
ao gun mose iwe e kan sOso ao se meteta be,
ojo tiaba se ise yi ni ao o bere sini lo ise yi. a
o bere we we ose yi nidede ago kan oru kun i
seju marun ao ma we ki ago kan to lu titi tiag
o kan yi fi bawa lori iwe yi,
Ojo akoko ao fiepo-pupara ara vwa ti ao to w
Ojo keji ao fiadin raara wa
Ojo keta ao fi Ori ra ara.
NOTE:- agbodo ti ma we ose yi ki ago kan oru
to lu(is a must we start bathing the soap bef
ore 1am) by Woli Irawo
10. ATUDE IMULE AGBA.
Opolo ijokumeta, obi abata alawe merin kan t
otobi kan, Orogbo kan, odidi atare kan, ao ki o
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
bi abata alawe merin yi boo polo akoko lenuo
didi atare bo opolo keji lenu ao kiorogbo nla
bo iketa lenu ao ko sinu agbada ao jo po ao lo
kuna dada ao mna fiepo pupa la ni ale ao ma fi
oti lo ni aro.
11. EYONUBIB0 ASIRI
Ori ijimere kan opolopo eso yerepe to po dad
aa ewe omisimisin gogoro ati pelebe, odidi at
are nla kan. ao fi ori ijimere tele inu ape ao fi a
tare si niegbe ao ko yerepe na leni ori ao wa k
O awon ewe omisinmisi mejiji le ni oriao waj
o po ao lo tiyio kunna dadaa ap ma fi oti (hot
gin) lo.
12.OSE EYONU
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
ao wa Esuru pupa ao gu po mo kanhun bilala
original ao po mose ao mafi we pelu omi to lo
Woro ni alale.
13.EYONUOSOLE TO MUOWO WA TARA
ao wa odidi olongbo to pe dada ao wa odidi a
tare meta, ewe orijin tagiri to kaje lara meta, ir
Uworo to po dadaa.
Sisere:- ao fi ologinitele ape ao ko atare mneta
na si niegbe ao je awon tagiri na si wewe ao k
o leori ao fi iruworo bo mole ao jo po ao lo ti
o yio kunna dadaa ao ma fi oyin gidi tabi oti lo
(by woli Henry Arole
14.EYONUARAYE
ao wa ewe ooyo (ewedu) tio lale wu fun rare
ao ja gbogbo ewe ara re lati isale lo si oke ao
wa gun pelu ewe alupaida iyekiye ao wa fiori
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
po pa po ao ma fi ra idodo wa jade peluofore
ofore:- omo araye eyonu simi atiokurin atiobi
nrin eyonu simimoti ja ewe ooyo, ooyo loniki
eyonu simi alupaida pa ibi da ko so ibi dire fu
n emi L-L loni
NOTICE:- ati isale ni o ja ewe ooyo na o0.
15.0SE EYONU
ao wa ifun okete oojo, epo-obo die,ewe oo
yo, ewe sinkirinmini, itana imi esu ao gun g
bogbo re pa po pelu ori ao wa fi eyin ororo
meta po mo ose dadaa ao wa kosi inu igb
a ete. (igba onikoko) ao ma fi epo-pupa ra
ra we nialele
16.EYONURIRISE
ao wa oriologini (cat head) ewe rekureku,
ewe sawerepepe, odidi atare kan ao jo p0
ao wa lo pelu sugar onikoro marun ao ma I
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
a ni araro. by Woli Henry Arole
17.£YONUOSOLE
Abo Olongbo aye nla kan, eye kowe olori dudu ka
n, ewe ola topo daada, atare nla meta. ao pa olog
ini niipa awo, ao la olongbo yini aya lati idi re ao
gbe kowe yi sinu re ao fi atare kan si elgbe, aofi
OWu dudu ati funfun ran pada ao wa fi atare kan
ha ni enu, ti koni wole tan ao gbe sinuagbada ao
fiatare to kun si ni egbe ao wa da ewe ola gbo m
ole ao jo po ao ro sinu igo funfun tabi inu aato
ao ma fimu eko gbigbona pelu ori ni alale.
18.EYONUASIRI BIBO
ao lo wa ewe kilofimise topo die suku agbado ori
akitan topo die, odidi atare kan ao jo po ao ro sibi
kana o mafi foko tutu mu laaro odaju.
19.0SEEYONU AWONAGBA
ewe rinrin to po ni won baa o gun pelu epo-obo di
e. ao pO mose ao wa le Ose na mo ogiri ibe ni ao
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
ma ti bu we
20.EYONUAWON AGBA TIENIYAN FI MARI
ORE GBA
ao wa ako eye ega eyo kan, oga ibile kan odidi at
are kan epo-obo tofe die, opolopo ewuro oojo
sesere:- ao wa ape tuntun ti aoti yo owWO oja kuro
lara re, ao fi epo-obo to fe yi tele ape ao gbe ako
eiye ega sori epo-obo ao fi oga ibile yen si legbe
ao fi atare si larin ao da ewuro le ori ao jo po ao d
a milk olope ati oyin igan pelu hot papo meteta a
o da papo ti ao mafi lo ise yi..
NOTICE:- ao bo aro yen ki ato bere si ni jo ise yi bi
be ko ogun na yio danu 00. ire o00000.
21.EYONUIFERANAYE TODAJU
ewe ewuro oojo to po die ao gun tiyio kunna
ewe sawerepepe oojo ao gun po mo tiyio kun
na ao gun mo ose ao fi ori po ao ko sinu ike f
unfun ao ma we lararo
1
Made with Xodo PDF Reader and Editor
22.EYONU ASINA
ewe ola tutu a le lo gbigbe na sungbo tutu lo
da ju. pelu ewe etiponola tutu ao gun po pelu
ose ao ko sinu ike funfun, ao ma fi we lararo
by Alfa Aridunu
23. EYONU AWON AGBA
ao lo wa aidan ao jo abi kao sun nina ao wal
o tiaba ti lotan ,ao te nieji ogbe ao pe ohunr
e siao ma fiepo pupa la lalale
OUNRE: kobira, kobira, sa gbadira gbagbasa
nle,kobira, oluruko tianpe iwo iku, kobira loru
koti npe iwo arun, sagbdira nioruko tỉn anpe i
wo sonpona gbagbasanle loruko ti anpe yin iy
ami osoro mofia, nigbati eyin mererin ti enti ik
ole orun bo wa si ikole aye, woni kini emu low
o esope aidan le mu lowo, Won ni kile mo fi ai
dan owo yin se?e sope e ma fidan omo aray
e wo nje emilagbaja omo lagbaja moti diom
o yin loni o, ema fi aidan owo yin dan mi emafi
aburu ise owo yin ni dan mi wo ire owo yin ni k
Made with Xodo PDF Reader and Editor
i e mafid an mi wo ire owo ni kie ma fi wa mi
kiri. ao ma fiepo la lalale. opari
24.EYONU TION MASA ENIYAN DA EY
AN NLA
Ao wa eye adan 16,eye onbe 16 eyin ororo 16
odidi atare 16, ao da opolopo ewe papansa b
o lorimole ao jo, ao lo kuna, ao ro sibi kan, ao
koko fi epo ogere lo ninu fitila oloju merind inl
ogun 16 fun 16 days, leyin na ao tun fi fokom
uninu igba fun 16 days ley in na ao wa ma fio
yin gidi la ninu awo funfun lemeta larin osu od
aju.
N.Bti a ba fiogere epo la fun 16 days tan ao t
un fifoko mu fun 16days telerawon nio. Odaj
25. EYONU AWON AGBALAGBA
Ao lo wa kowe olori dudu, ao lo wa ekuasin 1
6 ako alangba 16,eye onbe 16, ata ijosi topo
die, odidi atare kan, ewe origin oojo topo, epo
pupa igo kan, adin igo kan, ori topo.
Made with Xodo PDF Reader and Editor
SISERE:-ao da ata ijosi yi sinu ape ijugun, ao k
o awon eroyi le lori ao wa ko ewe orijin bo mo
le ao fi atare odidi kan si, ago mewa 10:pm ab
iago mokanla 11:pm. ni ama n bere sinijo is
e yi, a o fi epo pupa yika idi aro yi ki a to bere
sini jo ise yi ao jo tia ba jo tan ao lo leyin na ao
gbe epo pupa yi ati adin pelu ori sinuorun tiyi
o fi yo tio bayo tan ao gbe gbogbo ebuyi a
o dasi inu re a o gbe pamo fun ojo meta leyin
ojo meta a o mafin fako mu laro kutu kutu ki a
tojade odaju.
26. EYONUAYE TO DAJU TI ENIYAN FI
N GBE NKAN RERE
odidi adie opipieyo kan, oromo die ti won ses
e bieyo kan, ewe orijin oojo, ewe afeloru oojo,
epo obo to fimu dada ileke itun, ileke ifa, abee
re, eye ege pupa mejiao gun kuna papo dada
mose ao ko ose yi sisinu igba olomori abi ik
e funfun, a o gbe pamo fun 7days leyin 7days
a o ma buwe laro laro
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
27.EBUEYONUTIATUN LE FI GBE IPE
SE
Isu gbegbe, ao ge wewe we a o ko sinu ape
pelu odidi atare kan jo,a o lo kuna a o ro sinu i
go funfun kana biike funfun, a o fi epo la lalal
e, ti a ba fe fi se ipese a o bu die sori ipese a o
fi eposi a nugbe sita a o ma pe GBOLOHUN
RE:- si bayi pe begbe loni ki e gbe ire wa funm
i, ire owo, ire ola, ire Alafia aiku bale oro ni ko
ma wole tomiwa rere bayi nani a ma n soroat
are adua si odaju.
28.EYONU OSOSLEAWON AGBA
Olongbo Dudu kan, eiyele dudu kan, eye owiwi
kan, kowe kan, adan kan,igbin kan iye akala m
ewa, iye igbe mewa, iye aluko mewa, ikolode
mewa, iye lekeleke mewa, iye igun mewa, ewe
alupaida 200, ooyo 200,okete aye kan,jdero al
agbede, ase ale ati ase aro igi iroko, atare me
wa, enu opire, a oko gbogb0 re sinu ape nla k
Made with Xodo PDF Reader and Editor
an a o jo papo, a o lo kuna, a o ro sinu ara sere
nla, a o fiaso etu ran sere na,lara ao wapa ak
uko adie funfun si ara sere yen leyin naa ao tu
n paoruko ibile dudu kan siara sere na,a o wa
g be eje oruko yen sibikan, ao wag be ise yi s
inueje yen fun ojo meta leyin naa ao wa gbe i
seyi siaso asunwon funfun kan a o to irun igb
aja adie funfun yen siara ado yen ti a ti pa sit
an oo a o wa ma lo isee yi lekan larin osuni id
aji ni ago mejila opu 12:00am ni idaji osu eko
tutu ni ao mafi lo, a o si ni jeki ado na kanle
ma, ao fie ran yi atiadie yi se sara nioo aoni
je nibe odaju ire oo.
29.ENOYUASINA
ako alangba meta, Abo alangba meta, Egbo tu
de oojo atiewe tude oojo, pelu odidi atare me
ta, Sisere:- ao gbe awon ako alangba yi leraw
on ao gbe awon abo na lerawon ao wa ko aw
onatare si nilegbegbe aO wa ko egbo tude at
iewe re le lori ao jo ao fi po ose ao wa pin os
Made with Xodo PDF Reader and Editor
e yi si ona merinla 14 ao ma we pelu omi gbig
bona fun ojo merinla 14days odaju.
30.AKO EYONUAWON AGBA
ao wa ponri meje (7) epo-obo to fe to atelewo
opolopO ewe ewuro ao ko le lori mole ao fi at
are kan siao jo ao lo ao ro sinu ado ato. ao m
afi oti Lord lo tabi kiao mafi foko mu.
31.EYONUTO NSO ENIYAN DI NLA
ewe sinkirimi ao wa gun ewe yi pelu iyo ibilea
opo lose ao wa gbe epo, ori, ati adin sinu bor
un tiyio fiyo ao wa fipo ose yipa po ao sinu i
ke funfun tabi inu igba olomori
32.IMULE EYONU
Kowe oloridudu kan, pelu ori ao fi ori yi gbog
bo ara kowe yi ti ibi Kankan koni han sita mo
Made with Xodo PDF Reader and Editor
nibe ao gbe sinuagbada ijogun ao fi odidi ata
re kan si legbe ao jo ao wa ao wa tun gbe ori
miran sinu oruntiyio fiyo dada ao da ogun yi
sinu ori tiao gbe sinu orun ao mafi ma para
33.0GUN IBON
ao wa igo funfun bi igo lord ao bu iyo die sinu
igo naa, ao wa lo jaewe erinrin to po dadaa ao
wa ko sinu reao wag be pa mo si ibikan leyin
ojo ketayio tiro yio sisun omidadaa ao ma
muomi na die die.
34.0SE EYONU
Opolo gbigbe kan,eresile ewe lapalapa ao gu
npapo ti yio kuna ao po lose duduao maao
ma we ose yi ni alale ki a to sun pelu omi tolo
Woro
35.EYONU
ewe ejirin ao ti ja ewe yi sile lati irole ao wa eyi
n ororo 2/3 tio ba ti dioru ao wa bo ara si iho
ho ao wa gun ewe yi ni ihoho pelu eyin ororo y
iao wa ko sinu train kan(flat plate) ao wa gbe
Made with Xodo PDF Reader and Editor
sinuile ti yio figbe o ko gbodo gbe sinu orun
ooh tio batigbe tan ao wa lo die nibe pelu os
e ao da iyokusinu ipara ao mafi para odaju.
AKIYISI:- ose lux niao fi po ao si gbudo sa sin
uorun
36.0GUN IBON
Kuluso eyokan, eyo atare eyokan ao lo papoa
o fisin gbere eyokan si ibiegun tio ksin si kar
a ibadi wa nibi egun igegeru, ao fi ebu yisin g
bere eyokan sibe-odaju.
37.0GUN IBON
Ao wa kolofo isana tiao mo eniti olo isana inu
re, ao wa atare aja, ao fi sinu re, odidi atare aja
kan nio, ao jo, ao lo kuna? ao fi fokomu lekan
na ti won ba fe yin ibon mowa koni si ota ninu
re mo sugbon enikan lole loo ise yioo ijo ti a b
a jo ise yilo dara ju ki alo ise yi. Odaju
38.IKII IBON
Ti a ba ti jilaro kutukutu lai tisoro si enikan, a
Made with Xodo PDF Reader and Editor
o lo yagbe tiaba ti yagbe tan ao wa fi owu tut
u nu idi wa abi OWuakese ao finu idiwa nu, a
O wa we lowu imule, ao ran laWo tio ba wuwa
asi tun le mo ran lawo tia o ta mo inkan, eje ki
a danwo lara inkan abeemi ki a yin ibon si koni
wole si lara. Odaju.
39.EDA OBINRIN
Ogede omini, ao ko tele ape, ao ko o
polopo ewe rinrin lelori, ao fi omi re
niagbo tutu, leyin ojo keta, mimula
aro, lale
40.0KIGBE ATIOGUN IBON TIO DAJU
Ao lo wa opolo ijokun Tio tobi dada ti oni eji
ogbe leyin, ao lo wa oti lord abi oti schnapp ti
o je original ao wa ike funfun nla kan tia tiyo
OWo oja kuro lara re. ao muopolo yi ao ju sinu
ike funfun yen ao fi iderire de pada ao wa ti o
be gbigbona sinu ina ao wa fi lu ideri ike yi lor
i, ibe la o tiwar o oti yi siori opolo inu ike yen,
ao nijekiidi ike yen ko kanlemo ao wa file fun
Made with Xodo PDF Reader and Editor
bi wakati kan abo abi wakati kan 1 hours ori 1
V2 hours, leyin na opolo na yio tikun ao war o
otiyi pada sinu igo yen. ko gbodo kan ile oo e
ni na yio ma mu glass cup meji leyin 1hr. e jeki
a test rewo enina yio ma mu otiseku sugbon
oti na kO gbodo tan o ti won ba sawa ni ada k
oni ran wa tiwon ba sigun wa ni abere yio ma
kan ni o (eni kan lo le lo ise y)
41.ADARIN, OKIGBE
Opolo ijokun nla patapata ao gbe ogieko sori
ina ti ogi na ba tijina, ao mu opolo yen ao ju si
lori ina ao ro papo pelu re lori ina dada ao so
kan, ao ma mu diedie ni eko gbigbona yen, eni
yan pupa le lo ise yi ti won ba sawa lada koni r
an wa ti won ba sigun wa labeere koni wole si
wa lara. ODAJU.
42.0FO IBON
Ao je atare meje 7 lenu ao ma pe ofo yi :. LAB
UGE loruko tian pe iwo ogbe, ogbori aja fohu
Made with Xodo PDF Reader and Editor
n farabale loruko ti an pe iwo ofa ogborigi bun
a lorukoti an pe iwo ibon, Bi alagbede bar o iri
n atienure bole, Ibon nadojure ko emi lagbaja
omo lagbaja ki o ma tenu re bole bi alagbede
bar o irin atenu re bole, ofani won ba dojure k
o emi lagbaja omo lagbaja kio ma tenu re bol
e tori bi alagbede bar o irin atenu re bole.
43.0GUN ALEKO (MAN POWER)
Ao lo toju kanafuru, ata ile pupa, iyere, akogun
orogbo tutu, ao gun gbogbo sususu ao wa da
sinuhot tabi eniti koba kin lo hot ki a da sinu
omiorombo ki a ma mu glass cup kokan larar
44.ITOJUEGBO ADAJINA
Aowa omi osan tiwon ti fiomi la, a o da sori i
na tio bati ho tio ti so ao wa da ose dudu si
ao ma ro papo tio batise dada ao ro sinu ke
g kan, ao wa lo wa ikorahun igbin tisinu ti ao
ko mo enitioje, ao la ti yio kuna dada ao mak
Made with Xodo PDF Reader and Editor
un ikorahun igbi tia lo yi soju egbo na:
innso ge
45.0GUN TI AFINDE CLIENTI:-C
Ao lo wa alubosa funfun ti o tobi dada ao pani
pansa tiyio jin die ao wa mu photo client yen
okunrin ao ge ibi ori re nikan kuro ao fi ibi orir
eti a ge kuro yen tele inu alubosa ti a pa ni pa
nsa yen, ao wa lo wa yerepe ao ko sori client t
io wa ninu alubosa ti a fipa ni pansa yen ao t
un gen ori maga obinrin yen na ao wa tun ge o
riphoto tire na ao wa fi omorialubosa yen de
pada ao we lowu duduati owufunfun ao wa l
ori mo inu aro tiwon tin man dana ni gbogbo
igba ODAJU
46.0S0 TUTU
polo ijokun,tio tobidada, ao wa chewgum oj
uda ao ti bo lenu, ao tun tiirun iyamopo bo len
u ao sese wa fi ewe ola di kenu dada ao gbe s
inu agbada ao jo pelu odidi atare pelu hot lag
o kan oru1am.
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
47.0GUN EGBO ADAJINA
Ao lo wa akara ori akitan ao lo tiyio kana dad
a ao ma ku sioju egbo na yio pejude ni Kiakia.
48.0GUN TIA FI N DE CLIENT TO DAJ
Ao wa ako alangba kan ati abo alangba kan, e
re tako tabo ao wa ko oruko okunrin seyin ok
unrin oruko obinrin leyin obinrin ao wa mu eje
ako ao fir a ako ao mueje abo ao fi raabo ao
wa jo awon alangba yi pelu pada atare kan a o
jo ao lo ao wa di sinu paper white ao wa gbe
si aya awon ere mejeji yi ao di lowu imule ao I
ori si etiodo ODAJU.
49.ASEJE OSOLE
Ao lo wa ori oka tioni ase lenu, ao wa tun wa
atare ti on mi ninu ile re ao lo orioka ati ase re
yiao tun yo atare tion mi ninuile re yen na ao
lo papo mo ori atiase oka yen, nkan kan ko g
Made with Xodo PDF Reader and Editor
bodo yo danu ninu atare yen o ao lo kuna dad
a, ao lo wa eja aro tutu, ao pa ao ko ifun re jad
e ao gbe sinu isasun ao da ebu yi siao se lep
o niyo ao so sori osuka ao se adura si ao koje
ao mu omiaye le loriODAJU.
N.B:- Ninu isasun ti a ti yowo oja kuro lara re |
ao ti se aseje yio ODAJU.
50.EYONUGBOGBO AYE
Ao wa egungun olongini, ao lopelu eyo ataret
ikoniye ao wa lo ewe orijin na pelure, ao wa fi
eje ako atiabo alangba po papo ao wa dasi m
ejiao fiidakan p0 Ose, ao fi ida keji po ori ao
ma we Ose na ni idaji larin agogo marun si ag
ogo mefa 5am to 6am ao ma fi ikeji ra ori ido
do wa. ODAJU
51.0GUN EGBO ADAJINA
Ao wa epo obo ao lo kuna lenu ona ao wa pa
eje ako pepeye si ao fipo papo ao wafi singb
ere round oju egbo naa ao po ebu ti o seku yi
pelu ose ao ma fi we oju egbo na. ODAJU.
Made with Xodo PDF Reader and Editor
52.ISOYE
Eso iyeye tio po dada, a o jo pelu odidi atare
kan, ao lo pelu sugar oni koro iyekoye ao mal
o ni araro. ao ma da soju glass iriran ao ma la
nibe ODAJU.
53.0GUN EGBO ADAJINA
Ao la wa epo obo pelu alabukun, ao lo papo m
ora won ao ma kusi oju egbo na ODAJU.
54.0GUN EGBO ADAJINA
Ao lo wa epo obo ao lo tiyio po, bi sibi mefa,
ao wa lO wa alabukun yi o je bi sibikan abi me
jiao lo papo morawon be ao ma ku soju egbo
na, ao wa tun lo wa ewe iyalode mejeji ao gbo
peluomi tiyio ki dada ao wa koko fi fo oju eg
bo na leyin na ao ma wa ku ebuyen si loju OD
AJU.
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
55.0GUN WARAPA
Ao lo wa egbo bomubomu, ao tun lo wa erua
O wa re awon nkan wonyi pelu ito iya eniti war
apa muna ao fisile di ojo keji leyin naa ao ma
bu fun enitiwarapa nab a mu yio ma mu die d
ie. ODAJU. Akiyesi:- Ito idaji iya enina ni o.
56.GOUN ISOYE
Obi ipa alawe meta ao mu losi idi igi iroko ao
gba omi oje ara igi iroko si alara dada ao wa
mu losi ile pada ao je ki afefe fe si dada tio b
ati gbe mo lara ao fun omo na kioje, sungbo
n ao gbodo jeki o je kini kekere ti owani idiob
Iyen mO rara.
57.EGB0 ADAJINA
Ao wa orogbo ao bo epo arare ao lo epo ti ab
o larare yen ao ma kusi oju egbo na ODAJU.
58.EGB0 ADAJINA
Ao lo pa epo kashu tutu ao lo kuna ao sa ti yi
Made with Xodo PDF Reader and Editor
ogbe ao tun tunlo ao ma kusioju egbo yen 0
DAJU
59.0GUN IDI YIYI
Ao lo ewe taba gbigbe ao lo loju olo ao bu sib
Iepo pupa kan siao bu Ose dudu si ao fi ko a
o mafi tanba lemeji lojumo ODAJU.
60.0SE RIRISE.
Ojuoro, osibata, tutu ni ao loo, odidi at
are kan, ao lopo ao fiose iyekiye poo a
o ko sinu lke funfun ao ma fi we pelu o
fore bayi ti aba tibu sinu kainkain:- Oj
uoro nileke omi, osibata ni leke odo, e
mi. omo. ni kio ma leke awon ot
a
mi. Aowa lo fiwe. Ee meji lose niagbo
do we ose yi0.
61.INU RIRUN
Made with Xodo PDF Reader and Editor
O ko ogede, ao ge kekeke sinu ape, e
we agogoigun, odidi atare kan, ao jo
po, yio ma fiomi lasan lo diedie
62.EDA OBINRIN
Eemo agbo, opolopo irun ori ile barbe
r, odidi atare kan, ao jopo, aO ma fifo
eko tutumu
63.0YUN IJU
Epo isin, tabajuku, isu elu, ose dudu, o
polopo iyere, kanhunbilala, odidi atare
meta, ao Jopo mo ose dudu yen, ao b
u sinu hot, sibi kan laaro
64.ISETO*
Oka baba, aoyan bi guguru, ao lo nipo
wder, ao lo egbo akoogun na ni powder,
ao da po, aoma fi mu eko gbigbo
65.ITOJU OJUDIDUN
Made with Xodo PDF Reader and Editor
Kannafuru, kafura pelebe, egusi inues
o lapa funfun, aofo omiagbon kan si, ao
ma fiiye eyele kan sioju na
66 JEDIJEDI/YODIYODI
Ewe patanmo tewe tegbo, odidi atare
kan, ao po, ao po moori, fifi pa idi na
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
67 OLO INU
Egbo asuwon, orogbo gbigbe, Iminoj
o, isigun, egbo tude, egbo akoogun,
ata ijosi, ao gun po, tia bafe lo, a o
po iyo isebe mo iwon ba eyiti a ba fe
lo nibe
68 IDADURO OJO PIPE ENITIN WAOY
UN
ljapa kan, ao Jo ,ao da Omiagbon at
i odidi igo epo-pupa kan si Lori ina ,a
ojo po, yio ma fi fo eko tutu mu ti ob
ati pari nkanosu re kio to sunmo ok
Ore
69 HYPERTENSION(EJE RIRU)
Ewe eti erin aloe vera lopo, alubosa
aayu lopo, oyin igo kan, ao ge sinu ik
e, ao da oyin yen si, a o tun ro omi si
Made with Xodo PDF Reader and Editor
pelu, leyin ojo keta, short kan laaro at
ilale
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
70OHUNMO TODAJU
Ewe ogbo, ewe Iran, ewe omon, yere
pe gidi, odidi atare kan. Ao jo ti a ba f
e lo. ao te die sinu owo osi pelu ejiog
be... ha, ha, ha, ede oyo kojotegba te
gba kojo toyo odifa fun orunmila oojo
ti felomo ohun ti komo wo ilu re won
ni boni yiose ma mon oni omon ni yio
jeki ohun ma mon won ni boniyio se
magbo oni ogbo niyio jeki ohun mag
bo won ni boniyio sema ri oni iran ni
yio jeki ohun ma ri won ni boni kose n
sun asunpiye onitosan toruyerepe
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
kisun asunpiye emi lagbaja mofe m
o inkan bai ao wa fi owO osi fi fo pelu
eko elewe odidi kan ao gbemu ni iho
ho lago kan oru. ODAJUEBERE IBERE TIO
BAYE YIN MADA YIN LOHUN.. BY WOLIHENRY
AROLE.
71 AGBO TIABAFE FO INUFUN OBI
NRIN TI O BA TETE LOYUN TABI
OKUNRIN TIATO RE BA SAN
Bara kan, epa kun, ayu alubosa onisu p
upa, alubosa onisu funfun, alubosa ele
we. Ao wa re pelu stout sinu ike fun oj
o meta tiobinrin ba bere sisenka ale j
ore yio mamufun ojo marun okunrin yi
O mamu niaro ki o to jeun rara.
72 TI WON BADE OYUN MO OBIRIN
NINU
Made with Xodo PDF Reader and Editor
ao sa igbe Eran agutan atiewure tutu
tiyio gbe daada, ao lo kuna daada, ao
ro sinu igo kan pamo ao maa fi igbin
dudu se laseje fun oloyun eni tokan o
yun na ayi okuni kete naa,tia siko ati
bimore batito, tiobirin naa ba bimo.
LatiOwoWoliHenryArole
N.B Eje ki oloyun nawe ose ituwoA
Won Agba naa
73 OSE TA FIN WE GBOGBO IRAN
IKORIRA DANUNNU AIYE WA A
TIAGBO RE
Ao Wa Kanafuru. Kafura Pelebe. Imi
Ojo Dudu. Ao wa gun Won po Mose D
udu Ati Ose Funfun.
ao wa fiwe pelu agbo re fun ojo me
ta lera won.
Made with Xodo PDF Reader and Editor
L
*AGBO RE:
Ewe Koleorogba Tutu Topo Pelu Okunr
e. Ewe Ogbo Tutu Topo .Ao ko Eru Ala
ma Tele lkoko, ao wa buOmin Le Won
Mole .Aose Lagbo. Ao ma wa fiwe Os
e re Fun Ojo Meta Lera Won o daju Olo
run daju ju lo.
Lati Owo WoliHenryArole 99
74 AGB0 AWENUASIONA TODAJU
Ewe iyalode, ewe akoko, ewe aladun,
aogbo pa po ao fi iyo sibi kan si, aod
a sinu ike kan, ao ma mix e mo omi ti
ao lo mna fiwe lale ojo kokokan
75 AGBO IDAKOLE TODAJU
Kosiagbo kan to kappa idakole ju ba
ra lo, e lora bara, epa ikun, muru ko p
o die ao be bara yen ao ko egusi inur